Job 31:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
(láti ìgbà èwe rẹ̀ ni mo ti ń ṣe bíi baba fún un, tí mo sì ń tọ́jú rẹ̀ láti inú ìyá rẹ̀);
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe lati igba ewe mi wá li a ti tọ́ ọ dàgba pẹlu mi bi ẹnipe baba, emi si nṣe itọju rẹ̀ (opó) lati inu iya mi wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé láti ìgbà èwe mi wá ni a ti tọ́ ọ dàgbà pẹ̀lú mi bí ẹni pé baba, èmi sì ń ṣe ìtọ́jú opó láti inú ìyá mi wá: