Job 31:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Èyí pẹlu yóo jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀, tí adájọ́ gbọdọ̀ jẹ mí níyà fún; nítorí yóo jẹ́ aiṣootọ sí Ọlọrun ọ̀run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyi pẹlu li ẹ̀ṣẹ ìṣẹniṣẹ lọdọ awọn onidajọ, nitoripe emi iba sẹ́ Ọlọrun ti o wà loke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí pẹ̀lú ni ẹ̀ṣẹ̀ ti àwọn Onidàájọ́ ní bẹ̀wò. Nítorí pé èmí yóò jẹ́ aláìṣòótọ́ sí Ọlọ́run tí ó wà lókè.