Job 32:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Elihu, ọmọ Barakeli, ará Busi, ní ìdílé Ramu bá bínú sí Jobu, nítorí pé ó dá ara rẹ̀ láre dípò Ọlọrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni inu bi Elihu, ọmọ Barakeli, ara Busi, lati ibatan idile Ramu; o binu si Jobu, nitoriti o da ara rẹ̀ lare kàka ki o da Ọlọrun lare.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni inú bí Élíhù ọmọ Bárákélì ará Búsì, láti ìbátan ìdílé Rámù; ó bínú si Jóòbù nítorí ti ó dá ara rẹ̀ láre kàkà ki ó dá Ọlọ́run láre.