Job 32:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó ní, “Àgbàlagbà ni yín, ọmọde sì ni mí, nítorí náà ni ojú fi ń tì mí, tí ẹ̀rù sì ń bà mí láti sọ èrò ọkàn mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Elihu, ọmọ Barakeli, ara Busi, dahùn o si wipe, Ọmọde li emi, àgba si li ẹnyin; njẹ nitorina ni mo duro, mo si mbẹ̀ru lati fi ìmọ mi hàn nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Élíhù, ọmọ Bárákélì, ará Búsì, dáhùn ó sì wí pé: ọmọdé ní èmi àgbà sì ní ẹ̀yin; Ǹjẹ́ nítorí náà ní mo dúró mo sì ń bẹ̀rù láti fi ìmọ̀ mi hàn yin.