Job 33:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Jobu, n óo dá ọ lóhùn, nítorí pé bí o ti wí yìí, bẹ́ẹ̀ kọ́ lọ̀rọ̀ rí. Ọlọrun ju eniyan lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, ninu eyi iwọ ṣìna! emi o da ọ lohùn pe: Ọlọrun tobi jù enia lọ!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Kíyèsí i, nínú èyí ìwọ sìnà! Èmí o dá ọ lóhùn pé, Ọlọ́run tóbi jù ènìyàn lọ!