Job 33:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu àlá, lójú ìran ní ààrin òru, nígbà tí eniyan bá sun oorun àsùnwọra, lórí ibùsùn wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu àla, li ojuran oru, nigbati orun ìjika ba kùn enia lọ, ni isunyẹ lori bùsun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú àlá, ní ojúran òru, nígbà tó orun ìjìká bá kùn ènìyàn lọ, ní sísùn lórí ìbùṣùn,