Job 33:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí angẹli kan bá wà pẹlu rẹ̀, tí ó wà fún un bí onídùúró, àní, ọ̀kan láàrin ẹgbẹrun, tí yóo sọ ohun tí ó tọ́ fún un,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi onṣẹ kan ba wà lọdọ rẹ̀, ẹniti nṣe alagbawi, ọkan ninu ẹgbẹrun lati fi ọ̀na pipé han ni:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Bí oníṣẹ́ kan ba wà lọ́dọ̀ rẹ̀, ẹni tí ń ṣe alágbàwí, ọ̀kan ninú ẹgbẹ̀rún láti fi ọ̀nà pípé hàn ni,