Job 33:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
tí yóo ṣàánú rẹ̀, tí yóo sì wí pé, ‘Ẹ gbà á sílẹ̀, ẹ má jẹ́ kí ó lọ sinu ibojì, mo ti rí ìràpadà kan dípò rẹ̀.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni o ṣore-ọfẹ fun u, o si wipe, Gbà a kuro ninu ilọ sinu ihò, emi ti ri irapada!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ó ṣe oore ọ̀fẹ́ fún un ó sì wí pé, gbà á kúrò nínú ìlọ sínú ìsà òkú èmi ti ràá pàdà;