Job 33:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
nígbà náà eniyan óo gbadura sí Ọlọrun, Ọlọrun óo sì gbọ́ adura rẹ̀. Eniyan óo wá fi ayọ̀ wá siwaju Ọlọrun, yóo sì ròyìn ìgbàlà Ọlọrun fún gbogbo aráyé
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O gbadura sọdọ Ọlọrun, on o si ṣe oju rere si i, o si mu enia ri oju rẹ̀ pẹlu ayọ̀, on o san ododo rẹ̀ pada fun enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó gbàdúrà sọ́dọ̀ Ọlọ́run, òun sì se oju rere rẹ̀, o sì rí ojú rẹ̀ pẹ̀lú ayọ̀, òhun o san òdodo rẹ̀ padà fún ènìyàn