Job 34:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹni tí ó tó pe ọba ní eniyan lásán, tí ó tó pe ìjòyè ní ẹni ibi;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O ha tọ́ lati wi fun ọba pe, Enia buburu ni iwọ, tabi fun awọn ọmọ-alade pe, Alaimọ-lọrun li ẹnyin?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
O ha tọ́ láti wí fún ọba pé, ènìyàn búburú ní ìwọ, tàbí fún àwọn ọmọ aládé pé, ìkà ni ẹ̀yin;