Job 34:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ẹni tí kì í ṣe ojuṣaaju fún àwọn ìjòyè, tí kì í sì í ka ọlọ́rọ̀ sí ju talaka lọ, nítorí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ ni gbogbo wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ambọtori fun ẹniti kì iṣojuṣaju awọn ọmọ-alade, tabi ti kò kà ọlọrọ̀ si jù talaka lọ, nitoripe iṣẹ ọwọ rẹ̀ ni gbogbo wọn iṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ańbọ̀tórí fún ẹni tí kì í ṣójúṣàájú àwọn ọmọ-aládé tàbí tí kò kà ọlọ́rọ̀ sí talákà lọ. Nítorí pé iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ ni gbogbo wọn í ṣe?