Job 34:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé ojú rẹ̀ tó gbogbo ọ̀nà tí eniyan ń tọ̀, ó sì rí gbogbo ìrìn ẹsẹ̀ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe oju rẹ̀ mbẹ ni ipa-ọ̀na enia, on si ri irin rẹ̀ gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nítorí pé ojú rẹ̀ ń bẹ ní ipa-ọ̀nà ènìyàn, òun sì rí ìrìn rẹ̀ gbogbo.