Job 34:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Á máa jẹ wọ́n níyà ní gbangba, nítorí ìwà ibi wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O kọlu wọn bi enia buburu, nibiti awọn ẹlomiran ri i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó kọlù wọ́n nítorí ìwà búburú wọn níbi tí àwọn ẹlòmìíràn rí i,