Job 34:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé wọ́n kọ̀ láti tẹ̀lé e, wọn kò náání ọ̀nà rẹ̀ kankan,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni nwọn pada kẹhinda si i, nwọn kò si ti fiyesi ipa-ọ̀na rẹ̀ gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nítorí pé wọ́n padà sẹ́yìndà sí i, wọn kò sì fi yè sí ipa ọ̀nà rẹ̀ gbogbo,