Job 34:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Bí Ọlọrun bá dákẹ́, ta ló lè bá a wí? Nígbà tí ó bá fi ojú pamọ́, orílẹ̀-èdè tabi eniyan wo ló lè rí i?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati o ba fun ni ni irọra, tani yio da a lẹbi, nigbati o ba pa oju rẹ̀ mọ, tani yio le iri i? bẹ̃ni o ṣe e si orilẹ-ède tabi si enia kanṣoṣo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ṣùgbọ́n nígbà tí ó bá dákẹ́ síbẹ̀, ta ni yóò dá lẹ́bi? Nígbà tí ó bá pa ojú rẹ̀ mọ́, ta ni yóò lè rí i? Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe é orilẹ̀ èdè tàbi sí ènìyàn kan ṣoṣo;