Job 35:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n kígbe níbẹ̀ ṣugbọn kò dá wọn lóhùn, nítorí ìgbéraga àwọn eniyan burúkú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni nwọn ke, ṣugbọn Ọlọrun kò dahùn nitori igberaga awọn enia buburu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni wọ́n ń ké ṣùgbọ́n Ọlọ́run kò dáhùn nítorí ìgbéraga ènìyàn búburú.