Job 35:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jobu kàn ń la ẹnu, ó sì ń sọ̀rọ̀ lásán ni. Ọ̀rọ̀ rẹ̀ pọ̀, ṣugbọn kò mú ọgbọ́n lọ́wọ́.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni Jobu ṣe ya ẹnu rẹ̀ lasan, o sọ ọ̀rọ di pupọ laisi ìmọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ní Jóòbù se ya ẹnu rẹ̀ lásán ó ṣọ ọ̀rọ̀ di púpọ̀ láìsí ìmọ̀.”