Job 35:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Àwọn eniyan ń kígbe nítorí ọpọlọpọ ìnira, wọ́n ń bẹ̀bẹ̀ fún ìrànlọ́wọ́, nítorí àwọn alágbára ń tẹ̀ wọ́n mọ́lẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nipa ọ̀pọlọpọ ininilara nwọn mu ni kigbe, nwọn kigbe nitori apá awọn alagbara.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nípa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìninilára, wọ́n mú ni kígbe; wọ́n kigbe nípa apá àwọn alágbára.