Job 36:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí wọ́n bá gbọ́ràn, tí wọ́n sì sìn ín, wọn yóo lo ọjọ́ ayé wọn pẹlu ìdẹ̀rùn, wọn yóo ṣe ọ̀pọ̀ ọdún ninu ìgbádùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi nwọn ba gbagbọ, ti nwọn si sin i, nwọn o lò ọjọ wọn ninu ìrọra, ati ọdun wọn ninu afẹ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí wọ́n bá gbàgbọ́ tí wọ́n sì sìn ín, wọn ó lo ọjọ́ wọn ní ìrọ̀ra, àti ọdún wọn nínú afẹ́.