Job 36:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
A máa lo ìpọ́njú àwọn tí à ń pọ́n lójú láti gbà wọ́n là, a sì máa lo ìdààmú wọn láti ṣí wọn létí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On gba otoṣi ninu ipọnju rẹ̀, a si ṣi wọn li eti ninu inilara.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun gba òtòsì nínú ìpọ́njú wọn, a sì sọ̀rọ̀ sí wọn ní etí nínu ìnira wọn.