Job 36:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ranti láti gbé iṣẹ́ rẹ̀ ga, tí àwọn eniyan ń kọrin nípa rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ranti ki iwọ ki o gbe iṣẹ́ rẹ̀ ga, ti enia ima kọrin si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Rántí kí ìwọ kí ó gbé iṣẹ́ rẹ̀ ga, ti ènìyàn ni yín nínú orin.