Job 36:31 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe ń ṣàkóso àwọn orílẹ̀-èdè; ó sì ń fún wọn ní oúnjẹ lọpọlọpọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe nipa wọn ni nṣe idajọ enia, o fun ni li onjẹ li ọ̀pọlọpọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nitorí pé nípa wọn ní ń ṣe dájọ́ àwọn orílè èdè ènìyàn; ó sí ń pèsè oúnjẹ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀.