Job 36:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kìí mú ojú kúrò lára àwọn olódodo, ṣugbọn a máa gbé wọn sórí ìtẹ́ pẹlu àwọn ọba, á gbé wọn ga, á sì fi ìdí wọn múlẹ̀ títí lae.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On kì imu oju rẹ̀ kuro lara olododo, ṣugbọn pẹlu awọn ọba ni nwọn wà lori itẹ; ani o fi idi wọn mulẹ lailai, a si gbe wọn lekè.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun kì ímú ojú rẹ̀ kúrò lára olódodo, ṣùgbọ́n àwọn ọba ni wọ́n wà lórí ìtẹ́; Àní ó fi ìdí wọn múlẹ̀ láéláé, a sì gbé wọn lékè.