Job 36:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn bí a bá fi ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ dè wọ́n, tí ayé wọn kún fún ìpọ́njú,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi a ba si dè wọn ninu àba, ti a si fi okun ipọnju dè wọn,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ó bá sì dè wọ́n nínú àbà, tí a sì fi okùn ìpọ́njú dè wọ́n,