Job 36:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
a máa fi àṣìṣe wọn hàn wọ́n, ati ẹ̀ṣẹ̀ ìgbéraga wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni ifi iṣẹ wọn hàn fun wọn, ati irekọja wọn ti nwọn fi gbe ara wọn ga.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni o ń sọ àwọn ohun tí wọn ti ṣe fún wọn, wí pé wọ́n ti ṣẹ̀ pẹ́lú ìgbéraga wọn.