Job 37:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n ń yípo lábẹ́ ìtọ́ni rẹ̀, láti mú gbogbo àṣẹ tí ó pa ṣẹ, lórí ilẹ̀ alààyè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn wọnyi ni a si yi kakiri nipa ilana rẹ̀, ki nwọn ki o le iṣe ohunkohun ti o pa fun wọn li aṣẹ loju aiye lori ilẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn wọ̀nyí i káàriri nípà ìlànà rẹ̀, kí wọn kí ó lé ṣe ohunkohun tí ó pa láṣẹ fún wọn lórí ilẹ̀ ayé.