Job 37:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, a gbọ́ ìró ohùn rẹ̀, ó sọ̀rọ̀ ninu ọlá ńlá rẹ̀, bí ìgbà tí ààrá bá sán, sibẹsibẹ kò dá mànàmáná dúró bí àwọn eniyan ti ń gbóhùn rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lẹhin manamana ohùn kan fọ̀ ramuramu, o fi ohùn ọlanla rẹ̀ sán ãrá: on kì yio si da ãrá duro nigbati a ba ngbọ́ ohùn rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn mọ̀nàmọ́ná Òun kan fọ̀ ramúramù; ó sì fi ohùn ọláńlá rẹ̀ sán àrá; òhun kì yóò sì dá àrá dúró nígbà tí ó bá ń gbọ́ ohùn rẹ̀.