Job 38:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni OLUWA dá Jobu lóhùn láti inú ìjì líle.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NIGBANA ni OLUWA da Jobu lohùn lati inu ìji ajayika wá o si wipe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ígbà náà ní OLÚWA dá Jóòbù lóhùn láti inú ìjì àjàyíká wá, ó sì wí pé: