Job 38:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
kí ìmọ́lẹ̀ lè tàn sí gbogbo ayé, kí ó sì lè gbọn àwọn ẹni ibi dànù, kúrò ní ibi ìsápamọ́sí wọn?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki o le idi opin ilẹ aiye mu, ki a le gbọ̀n awọn enia buburu kuro ninu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ó lè di òpin ilẹ̀ ayé mú, ki a lè gbọ́n àwọn ènìyàn búburú kúrò nínú rẹ̀?