Job 38:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Dájúdájú o mọ̀, nítorí pé wọ́n ti bí ọ nígbà náà, o sá ti dàgbà!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ mọ̀ eyi, nitoriti ni igbana ni a bi ọ? ati iye ọjọ rẹ si pọ!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ mọ èyí, nitorí nígbà náà ni a bí ọ? Iye ọjọ́ rẹ sì pọ̀.