Job 38:40 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
nígbà tí wọ́n bá dùbúlẹ̀ ninu ihò wọn, tabi tí wọ́n ba ní ibùba wọn?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati nwọn ba mọlẹ ninu iho wọn, ti nwọn si ba ni ibuba de ohun ọdẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí wọ́n bá ń mọ́lẹ̀ nínú ihò tí wọ́n sì ba ní ibùba de ohun ọdẹ?