Job 38:41 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ta ní ń wá oúnjẹ fún àwọn ẹyẹ ìwò, nígbà tí àwọn ọmọ wọn bá kígbe sí Ọlọrun, tí wọ́n sì ń káàkiri tí wọn ń wá oúnjẹ?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Tani npese ohun jijẹ fun ìwo? nigbati awọn ọmọ rẹ̀ nkepe Ọlọrun, nwọn a ma fò kiri nitori aili ohun jijẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ta ni ó ń pèsè ohun jíjẹ fún ìwọ, nígbà tí àwọn ọmọ rẹ ń ké pe Ọlọ́run, tí wọ́n sì máa ń fò kiri nítorí àìní ohun jíjẹ?