Job 39:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ògòǹgò lu ìyẹ́ rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ninu ọláńlá rẹ̀, ṣugbọn kò lè fò bí ẹyẹ àkọ̀?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iyẹ abo-ogongo nfi ayọ̀ fì, iyẹ ati ihuhu rẹ̀ daradara ni bi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ìyẹ́ abo ògòǹgò ń fi ayọ̀ fì; Ṣùgbọ́n a kò le fi àká we ara wọn ní ìyẹ́ àti ìhùhù