Job 39:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó fẹsẹ̀ walẹ̀ ní àfonífojì, ó yọ̀ ninu agbára rẹ̀, ó sì jáde lọ sí ojú ogun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O fi ẹsẹ halẹ ninu aporo, o si yọ̀ si agbara rẹ̀; o nlọ jade lati pade awọn ahamọra ogun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó fi ẹsẹ̀ halẹ̀ nínú àfonífojì, ó sì yọ̀ sí agbára rẹ̀; ó lọ jáde láti pàdé àwọn ìhámọ́ra ogun.