Job 39:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí fèrè dún, ó kọ, ‘Hàáà!’ Ó ń gbóòórùn ogun lókèèrè, ó ń gbọ́ igbe ọ̀gágun tí ń pàṣẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O wi ni igba ipè pe, Ha! Ha! o si gborùn ogun lokere rere: ãrá awọn balogun ati ihó àyọ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó wí nígbà ìpè pé, Háà! Háà! Ó sì gbóhùn ogun lókè réré, ara àwọn balógun àti ariwo ogun wọn.