Job 39:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ wọn á di alágbára, wọn á dàgbà ninu pápá, wọn á sì lọ, láìpadà wá sọ́dọ̀ àwọn òbí wọn mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ wọn ri daradara, nwọn dagba ninu ọ̀dan, nwọn jade lọ, nwọn kò si tun pada wá mọ́ sọdọ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ wọn rí dáradára, wọ́n dàgbà nínú ọ̀dàn; wọ́n jáde lọ, wọn kò sì tún padà wá sọ́dọ̀ wọn.