Job 4:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kinniun alágbára a máa kú, nítorí àìrí ẹran pa jẹ, àwọn ọmọ abo kinniun a sì fọ́nká.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ogbo kiniun kígbe, nitori airi ohun-ọdẹ, awọn ẹ̀gbọrọ kiniun sisanra li a tukakiri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ógbó kìnnìún kígbe, nítorí àìrí ohun ọdẹ, àwọn ẹ̀gbọrọ kìnnún sísanra ni a túká kiri.