Job 4:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀mí kan kọjá fìrí níwájú mi, gbogbo irun ara mi sì dìde.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni iwin kan kọja lọ niwaju mi, irun ara mi dide ró ṣanṣan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni iwin kan kọjá lọ ní iwájú mi, irun ara mi dìde ró ṣánṣán.