Job 40:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wo gbogbo àwọn agbéraga, kí o sì sọ wọ́n di yẹpẹrẹ, rún àwọn ẹni ibi mọ́lẹ̀ ní ipò wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wò gbogbo ìwa igberaga, ki o si rẹ̀ ẹ silẹ, ki o si tẹ enia buburu mọlẹ ni ipo wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wo gbogbo ìwà ìgbéraga, ènìyàn kí o sì rẹ ẹ sílẹ̀, kí o sì tẹ ènìyàn búburú mọ́lẹ̀ ní ipò wọn.