Job 40:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni OLUWA tún bá Jobu sọ̀rọ̀ láti inú ìjì líle, ó ní,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni OLUWA da Jobu lohùn lati inu ìji ajayika wá o si wipe:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ní OLÚWA sọ̀rọ̀ fún un láti inú ìjì àjàyíká wá, ó sì wí pé: