Job 41:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ìpẹ́ náà lẹ̀ mọ́ ara wọn tímọ́tímọ́, tóbẹ́ẹ̀ tí afẹ́fẹ́ kò lè fẹ́ kọjá láàrin wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ekini fi ara mọ ekeji tobẹ̃ ti afẹfẹ kò le iwọ̀ arin wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èkíní fi ara mọ́ èkejì tóbẹ́ẹ̀ tí afẹ́fẹ́ kò lè wọ àárin wọn.