Job 41:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí ó bá dìde, ẹ̀rù á ba àwọn alágbára, wọn á bì sẹ́yìn, wọn á ṣubú lé ara wọn lórí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati o ba gbe ara rẹ̀ soke, awọn alagbara a bẹ̀ru, nitori ìbẹru nla, nwọn damu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ó bá gbé ara rẹ̀ sókè, àwọn alágbára bẹ̀rù; nítorí ìbẹ̀rù ńlá, wọ́n dààmú.