Job 41:34 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó fojú tẹmbẹlu gbogbo ohun gíga, ó sì jọba lórí gbogbo àwọn ọmọ agbéraga.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O bojuwo ohun giga gbogbo, o si nikan jasi ọba lori gbogbo awọn ọmọ igberaga.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó bojú wo ohun gíga gbogbo, ó sì nìkan já sí ọba lórí gbogbo àwọn ọmọ ìgbéraga.”