Job 5:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó mú àwọn ọlọ́gbọ́n ninu àrékérekè wọn; ó sì mú ète àwọn ẹlẹ́tàn wá sópin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O mu awọn ọlọgbọ́n ninu arekereke ara wọn, ati ìmọ awọn onroro li o tãri ṣubu li ògedengbè.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó mú àwọn ọlọ́gbọ́n nínú arékerekè ara wọn, àti ìmọ̀ àwọn òǹrorò ní ó tari ṣubú ní ògèdèǹgbé.