Job 5:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn arọmọdọmọ rẹ yóo pọ̀, bí ewéko ninu pápá oko.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ o si mọ̀ pẹlu pe iru-ọmọ rẹ yio si pọ̀, ati awọn ọmọ-ọmọ rẹ yio ri bi koriko ìgbẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ ó sì mọ̀ pẹ̀lú pé irú ọmọ rẹ ó sì pọ̀ àti àwọn ọmọ ọmọ rẹ yóò rí bí koríko ìgbẹ́.