Job 6:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn, ẹ̀yin arakunrin mi, ẹlẹ́tàn ni yín, bíi odò àgbàrá tí ó yára kún, tí ó sì tún yára gbẹ,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ará mi ṣẹ̀tan bi odò ṣolõ, bi iṣàn gburu omi odò ṣolõ, nwọn ṣàn kọja lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ará mi ṣọ̀tẹ̀ bí odò sólo bí ìṣàn gúru omi odò sólo, wọ́n ṣàn kọjá lọ.