Job 6:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ṣugbọn ní àkókò ooru, wọn a yọ́, bí ilẹ̀ bá ti gbóná, wọn a sì gbẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbakũgba ti nwọn ba gboná, nwọn a si yọ́ ṣanlọ, nigbati õrùn ba mú, nwọn si gbẹ kurò ni ipò wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà kúgbà tí wọ́n bá gbóná wọn a sì yọ́ ṣànlọ, nígbà tí òòrùn bá mú, wọn a sì gbẹ kúrò ni ipò wọn.