Job 6:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn oníṣòwò tí ń lo ràkúnmí yà kúrò ní ọ̀nà wọn, wọ́n ń wá omi kiri wọ́n kiri títí wọ́n fi ṣègbé ninu aṣálẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iya ọ̀na wọn a si yipada sapakan, nwọn goke si ibi asan, nwọn si run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìyà ọ̀nà wọn a sì yípadà sí apá kan, wọ́n gòkè sí ibi asán, wọ́n sì run.