Job 6:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìrètí wọn di òfo nítorí wọ́n ní ìdánilójú. Wọ́n dé ibi tí odò wà tẹ́lẹ̀, ṣugbọn òfo ni wọ́n bá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn dãmu, nitoriti nwọn ni abá; nwọn debẹ̀, nwọn si dãmu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n já lulẹ̀, nítorí tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ wọn lée; wọ́n débẹ̀, wọ́n sì dààmú.