Job 6:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ìbá wúwo ju yanrìn etí òkun lọ. Ìdí nìyí tí mo fi ń fi ìtara sọ̀rọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ nisisiyi, iba wuwo jù iyanrin okun lọ: nitorina li ọ̀rọ mi ṣe ntàse.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ǹjẹ́ nísinsìn yìí, ìbá wúwo jú iyánrìn òkun lọ: nítorí náà ni ọ̀rọ̀ mi ṣe ń tàsé